
Author: Toju Ogbe
ASA: Iba

Oru sẹ ileku,
 I wanna have some talk, with you-o
 Nitori rẹ mo sẹ lola
 Nitori rẹ mo sẹ sogẹ
 Nitori rẹ mo sẹ ra moto
 Mo wo lẹ, mo boluwa mi soro
 Nitori rẹ mo sẹ wa laiye 
 Nitori rẹ mo sẹ wa so sara 
 Nitori re moji lowuro 
 Mo wo aye mi lo de ye ya
Aa aho ha ha a ha
 Iba fi ele
 iba fi eledua
 Aa ho ho a ho 
 Mo mo le ye
 mo boluwa mi soro
Nitori re mo sẹ gbo
 Iroyin ayo
 lai so owo
 lai si nkan kan
 I ya oni layo la o o
 boluwa se wi be na lori 
 Oh oh o wi kpe kim ma se beru
 So aho ho a ho a a ho…
