
Oju mo ti mo
 Oju mo ti mo mi
 Ni le yi o o
 Oju mo ti mo – mo ri re o
 Eye adaba 
 Eye adaba
 Eye adaba ti n fo lo ke lo ke
 Wa ba le mi o o
 Oju mo ti mo mo ri re o
The most reliable platform for presenting the best of Nigeria – positive diplomacy and foreign relations news; diplomatic strategy; international development jobs; policy review; value inspired role models; good music, humour, art and culture; history, etc.

Oju mo ti mo
 Oju mo ti mo mi
 Ni le yi o o
 Oju mo ti mo – mo ri re o
 Eye adaba 
 Eye adaba
 Eye adaba ti n fo lo ke lo ke
 Wa ba le mi o o
 Oju mo ti mo mo ri re o

Bimpe nba mi wi
 Ofowo sinu business mi
 Emi ire ko legbe
 Oko saju mi bimo ni
 Mogbo npe o momi loju
 Oun nla ni gboa nipa business mi
 Oro emi ire ko le ni
 Egbon re femi ni
 Egbon re ton femi lowo ni o
 Mo ti ya fun
 Egbon re egbon re ha

Ma ya lé mi iwo orè atojubo onilé
 Ma ya lé mi iwo orè agbok’oloko
 Ma ya lé mi awon orè adugbo
 Ma ya lé mi ma ya lé k’omo
 Orè ti mo mu bi aburo
 Orè, orè ti mo sé daara dara
 Orè ti mo fi nu hun
 Owa daami o tumi sita
 Odabi oro ano
 Bi oro ano