
Era ile, era ile
 Won yin baba l’oke
 Yanrin okun, yanrin okun
 Won n yin baba l’oke
 Eranko ile, eranko igbo Won n yin baba l’oke
 Awon alaini, awon tan ti ni
 Won yin baba l’oke
 [CHORUS:]
 Ko se igbati nkan ba se yan
 Ko to mo pe baba n be l’oke
 Ko se igbati nkan ba se yan
 Ko to mo pe looto o n be l’oke
 You don’t have to wait till you feel the pain
 You can start right now
 It’s not too late
 It’s not too late, to be grateful