
Oh ah! mo gbon pké
 Eyin ni broder oké
 Eyin le ko mo mi lo lé ah ah ah
 Oh ah! mo gbon pké
 Eyin ni sista oké
 Eyin le nfe broder olé, ah ah ah
 Iya sidi oni diri mi
 Sisi uche egbon ore mi
 Awon lo ran mi wa o o yo o o
 Bobo musa oni réké wa
 Iya mulika olomo méjé
 Awon lo ran mi wa o o yo o o